Aárò Dino ń sọ àwọn aṣòfin; Mammadou dọmọ onilu ni France

Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.

Attahiru Jega pe àwọn Asòfin ní olè

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán,

Àwọn Asòfin Naijiria fẹ́ràn gbígba owó ẹ̀bùrú

Alaga ajọ to ń rísí ètò ìdìbò Nàìjíríà (INEC) tẹlẹri, Ọjọgbọn Attahiru Jega, ni ọ̀nà àbáyọ ni ki a dẹ́kun rìbá gbígbà ni Naijiria.

Jega sọ ọrọ yii nibi to ti n se idanilẹkọọ lori ayajọ Ọjọ Iṣejọba Tiwantiwa (Democracy Day) t'ọdun yii ni Abuja lorilẹ-ede Naijiria.

Nigeria vs DR Congo: Eagles gbá ọ̀mì pẹ̀lú Leopard ní Pọtá

Àkọlé àwòrán,

Orilẹ-ede Naijiria wa lara orilẹ-ede marun un lati ile Afrika ti yoo kopa ni Russia 2018

Ìkọ agbaboolu Super Eagles orílè-èdè Nàìjíríà ati akẹgbẹ wọn láti orílè-èdè DR Congo ti gba àmì ayò kọọkan nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ọlọrẹsọrẹ

Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ náà wà lára ipalemo ìkọ Super Eagles ṣaaju ìdíje ife ẹyẹ àgbáyé to n bò lónà ní Russia. E ka ekunrere re ni bii

Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni

Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC

Fidio wa fun toni

Aliu Sodiq mú ìbẹ̀rù kúrò lọ́kàn àwọn ènìyàn nípà ìrírí mọ́ṣúàrì.

Àkọlé fídíò,

'Obìnrin tí kó ba fẹ́ òṣìṣẹ́ Mọ́ṣúárì, ìpinu rẹ̀ mẹ́hẹ'