‘Yorùbá ní àlùmọ́ọ́nì láti dá dúró’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Odùoyè: Àwọn àgbààgbà tó ti sèjọba kọjá yẹ kó lọ sinmi

Kayọde Oduoye, tíí se ọdọ́ olósèlú kan, ti korò ojú sí àwọn ohun àlùmọ́ọ́nì tó mẹ́hẹ tó wà ní ilẹ̀ Yorùbá, tó sì ń késí àwọn ọ̀dọ́ láti dìde gba ìjọba lọ́wọ́ àwọn àgbààgbà tó ń tukọ̀ orílẹ̀èdè yìí.

Ó ní ọ̀pọ̀ àwọn ohun àlùmọ́ọ́nì bíi omi tó tẹ́jú àti ilẹ̀ tó gbòòrò ni ilẹ̀ yorùbá ní láti dá dúró láì gbára lé owó ìjọba àpapọ̀.

Bákan náà ló sàlàyé pé táa bá wo ọ̀pọ̀ àǹfàànì tí ilẹ̀ yorùbá ní sẹ́yìn, ipò tí a wà yìí kò bójúmu tó.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: