'Isẹ́ Tíátà tí mò ń se ti tó mi jẹun'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Tọpẹ Adebayọ: Isẹ́ Tíátà tí mò ń se ti tó mi jẹun

Temitọpẹ Adebayọ jẹ ọmọ Ọga Bello, àgbà olósèré Yoruba òun gan sì ti ń m'ókè nínú isẹ́ tí baba fi lé e lọ́wọ́.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: