Justice Mustapha Akanbi f'ayé sílẹ̀ lẹ́ni ọdún 85

Adájọ́ Àgbà Mustapha Akanbi Image copyright Abdul Momoh
Àkọlé àwòrán Justice Mustapha Akanbi f'ayé sílẹ̀

Adájọ́ Àgbà Mustapha Akanbi ti re 'bi àgbà ń rè. Òsìsẹ́fẹ̀yìntì ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn tó tún jẹ́ alága àkọ́kọ́ àjọ tó ń gbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá ICPC papòdà ní àfẹ̀mójúmọ́ òní, ọjọ́ àìkú, ọjọ́ kẹta osù kẹ́fà ọdún 2018 lẹ́yìn àìsàn ráńpẹ́.

Olóògbé Wàkílì ti ilú Ilọrin f'ayé sílẹ̀ ní ẹni ọdún márùndínláàdọ́rin.

Ìsìnkú yóò wáyé lọsan ọjọ́ àìkú.

Àwọn abáni kẹdun sí ti n ṣe àbẹwò sí ilé olóògbé náà ni ìlú Ilorin.

Wọnyi ni akojopo àwòrán bi ètò ṣe n ló níbẹ.

Image copyright Abdul Momoh
Àkọlé àwòrán Adari Ajọ to n risi eto idanwo aṣewọle s'ile ẹkọ giga, JAMB Ojogbon Oloyede ati agba oje agbejoro Olaolu Alli
Image copyright Abdul Momoh
Àkọlé àwòrán Won gbe iwe ibanikedun kale ti awọn eeyan si n fọwọ si
Image copyright Abdul Momoh
Àkọlé àwòrán Ọpọ eniyan lo'n jaran Ologbee Akanbi

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

England na Nigeria pẹ̀lú àmi ayó 2- 1

Motunrayo Adeoye: Ọgbẹ́ inú mú òṣèré lọ

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionÌṣẹlẹ iyinbon APC Ekiti : Ki gaan lo ṣẹlẹ?

Related Topics