Abiola: Mo fẹ́ mọ ẹni tó jáwé olúborí nínú ìdìbò June 1993

Abiola: Mo fẹ́ mọ ẹni tó jáwé olúborí nínú ìdìbò June 1993

Lẹyin ti Aarẹ Muhammadu Buhari kẹdẹ June 12 gẹgẹ bii 'Ayajọ Ọjọ Isejọba tiwantiwa', ọmọ M.K.O. Abiola, Abdulmumini Abiola, ni inu oun dun lọpọlọpọ, oni ẹbun Ramadan pataki ni eyi jẹ fun oun.