Ìpànìyàn Plateau: Ọ̀pọ̀ ẹ̀mí sùn lẹ́yìn ìjà àgbẹ̀ àti darandaran

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló pàdánù ẹ̀mí wọn tí àwọn mìíràn sì farapa yánayàna lẹ́yìn ìkọlù láàrin àwọn àgbẹ̀ àti àwọn darandaran.

ọ̀kan lára àwọn tó ṣèèse nínú ìkọlù Plateau
Àkọlé àwòrán,

ọ̀pọ̀ èèyàn d'olóògbé lkyìn ìkọlù àgbẹ̀ àti darandaran

Àkọlé àwòrán,

Darandaran f'ẹ̀mí ọ̀pọ̀ èèyàn ṣòfò ní Plateau

Àkọlé àwòrán,

Ogunlọ́gọ̀ ló farapa nínú ìpàniyàn Plateau

Àkọlé àwòrán,

ọ̀pọ̀ ohun iní ló bàjẹ́ lẹ́yìn ìkọlù Plateau

Àkọlé àwòrán,

Ọ̀kan lára àwọn ọks akẹ́rù tó jóná lójú pópó níbi ìsẹ̀lẹ̀ náà

Àkọlé àwòrán,

ọ̀pọ̀ èèyàn d'olóògbé lkyìn ìkọlù àgbẹ̀ àti darandaran

Àkọlé àwòrán,

Rúkèrúdò ní Plateau lẹ́yìn ìpànìyàn tó ṣẹlẹ̀

Àkọlé àwòrán,

ọ̀pọ̀ ilé àti mọ́tọ̀ ni àwọn darandaran jó ní iná nínú ìkolù Plateau