‘Ki lo buru ninu keeyan wẹwu agbọta?'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

#EkitiDecides: Kayọde Fayẹmi ní wíwọ ẹ̀wù agbọta kò lòdì sí òfin

Olùdijé fún ipò gómìnà lábẹ́ àsìá ẹ́gbẹ́ òṣèlú APC sọ nípa bí ó ti ṣe se ètò ìjọba rí àti èyi tí yóò ṣe bó bá wọ́le.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí:

Àkọlé àwòrán Awọn oludije gomina l‘Ekiti