Thailand: Gbogbo àwọn agbábọ́ọ́lù náà láti yọ kúrò nínú ihò

Thailand
Àkọlé àwòrán Ìtúsílẹ̀ dé f'áwọn ọmọ tó jìn sí kòtò!

Gbogbo awọn ogo wẹẹrẹ mejila to jẹ agbabọọlu ni orilẹede Thailand ni wọn ti doola ẹmi wọn lẹyin ti wọn ha si inu iwo lati bi ọsẹ meji sẹhin.

Ile isẹ ọmọogun ilẹ Thailand to fi ọrọ naa lede sọ wi pe omuwe kọọkan lo gbe awọn ọmọ naa jade ni ẹyọ kọọkan.

Àkọlé àwòrán Ìtúsílẹ̀ dé f'áwọn ọmọ tó jìn sí kòtò!

Awọn omuwẹ ti ilẹ Thailand to bẹrẹ ni Ọjọ Isinmi lati doola ẹmi wọn, yọ mẹ́rin miran pẹlu awọn mẹrin ti wọn yọ tẹlẹ ni ọjọ keji igbiyanju lati yọ awọn ọmọ naa.

Image copyright Alamy
Àkọlé àwòrán Lẹyin ti wọn yọ mẹrin ninu awọn ọmọ naa ni ọjọ Isinmi, àwọn ẹlẹ́yinjú àànú ti yọ àwọn to ku kúrò nínú íhò.
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption‘Ki lo buru ninu keeyan wẹwu agbọta?'

Nibayii, iroyin sọ wi pe wọn gbogbo awọn omuwẹ mẹrin ati dokita to tọju awọn ọmọ naa ni inu iho ti wọn ha si ti jade si ita kuro ni inu iho ohun.

Related Topics