‘Wọ́n ti sọ Ìbò di kátà-kárà ní Èkìtì’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ekiti Decides: Abiọdun Aluko ní báwọn se kàwé tó l‘Ekiti, ìyà sì ń jẹ àwọn

Olùdíje fún ipò gómìnà nínú ẹgbẹ́ òsèlú Accord, Ọ̀mọ̀wé Abiọdun Aluko, lásìkò tó ń bá BBC Yorùá sọ̀rọ̀ ní àwọn isẹ́ tó nira láti se, tí gómìnà Ayọdele Fayose ń gbé fún òun, èyí tó leè pa òun lára, ló mú kí òun kúrò nínú ẹgbẹ́ òsèlú PDP ni sáà àkọ́kọ́ Fayose.

Aluko, nígbà tó ń dáhùn ìbéèrè lórí ìdí táwọn ọ̀dọ́ kò se kópa nínú ìbò gómìnà ní Èkìtì, tún sàlàyé pé àwọn ọ̀dọ́ gbọdọ̀ ní ìrírí, kí wọn tó leè díje fún ipò gómínà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé àwòrán Awọn oludije gomina l‘Ekiti