Ẹgbẹ́ òsèlú ADP yóò fọwọ́ kan ìsẹ́ l‘Èkìtì
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

#EkitiDecides: Sẹgun Adewale ní ìpèsè ohun ìdẹ̀rùn yóò bá ìfẹ́ aráàlú mu

Lásìkò tó ń bá ikọ̀ BBC Yorùbá sọ̀rọ̀, Ọmọọba Adeoy Adelaja, tíí se agbẹnusọ fún Olùdíje fún ipò gómìnà fẹgbẹ́ òsèlú ADP, Ọ̀túnba Sẹgun Adéwálé sọ pé, ifẹ́ tí ara ìlú ní sí òun ló mú kí wọn máa pe òun ní Osa pra-pra.

O ní gbogbo èèyàn ló fẹ́ràn ẹgbẹ́ ADP, tí òun sì ti setán láti mọ ibití ìsẹ́ ti ń báwọn aráàlú fínra.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé àwòrán Awọn oludije gomina l‘Ekiti