Yaa Asantewaa: Ti ẹyin ọkunrin Ashanti kò bá tẹsiwaju, awa obinrin yóò lọ

Itan akinkanju obinrin Yaa Asantewaa, to wa ninu itan orilẹede Ghana, ẹni to léwájú àwọn obìnrin tó koju ogun Gẹẹsi to fẹ gba ilẹ Ashanti, tawọn obinrin naa si bori.