‘Ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ni ìfètòsọ́mọbibi’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Stella Akinsọ: Àwọn Ìwé Mímọ́ fi àsẹ sí ìfètòsọ́mọbíbí

Onimọ nipa ifetosọmọbibi, Stella Akinso ni ẹtọ ọmọ eniyan ni ifeto si ọmọ bibi nitori yoo mu igbe aye alaafia ba ọpọ eniyan, eto ẹkọ yoo lo deede, ife yoo wa laarin ọkọ ati aya, ati wi pe yoo mu ibugbooro ba eto ọrọ aje ni orilẹede Naijiria.

Arabinrin naa wa parọwa si ijọba Naijiria ati gbogbo awọn ti ọrọ naa kan, lati pese ohun amayederun ati eto iwosan igbalode ti yoo mu ki ifeto si ọmọ bibi lọ ni irọwọrọsẹ.