Fídíò tó ń sọ bí ọlọpàá se kún ojú pópó l‘Ékìtì
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ekiti Election: Àwọn ohun èèlò ìdìbò ń dé síjọba ìbílẹ̀

Ní báyìí tó ku wákàkí péréte kí ètò ìdìbò Èkìtì gbéra sọ̀, Ìpalẹ̀mọ́ ti dé ojú ọ̀gbagadè fún ètò ìdìbò náà, pẹ̀lú àwọn ohun èèlò ìdìbò tó ti ń dé sáwọn ìjọba ìbílẹ̀ báyìí.

Bákan náà ni àwọn agbófinro náà gba àwọn ojú pópó kan láwọn ìlú tó wà ní ìpínlẹ̀ náà.

Ikọ̀ ìròyìn BBC Yorùbá tó wà ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ní àwọn agbófiró náà wà níbi tí wọn ti ń já àwọn ohun èèlò ìdìbò náà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: