Ile isẹ ọlọpaa: A n gbe Ọrẹkunrin Khadijat rẹlẹ ẹjọ ni Ọjọ Aje

Ile isẹ ọlọpaa: A n gbe Ọrẹkunrin Khadijat rẹlẹ ẹjọ ni Ọjọ Aje

Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ kan tí wọ́n ti ń wá Khadijat tó jẹ́ ọmọ igbákeji gómínà tẹ́lẹ̀rí ní ìpínlẹ̀ Ondo, wọ́n bá òkú rẹ̀ ní ilé àfẹ́sọ́nà rẹ̀.

Ọpọlọpọ iroyin lo n jẹyọ lori isekupani Khadijat Olubọyo, sugbon Ileese Olọpaa ni ipinlẹ Ondo ni awọn ko gba ọrọ ọrẹkunrin Khadijat gbọ wipe, oun kọ loun pa ọmọbinrin naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: