World Cup: Ambode sanwo ènìyàn 50 ní Russia
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Russia 2018: ọjọ́ 11 ní à ò fí jẹun tí à kò sùn

O fi kún un pé, ọpẹ́lọpẹ́ Gomina ìpínlẹ̀ Eko Akinwumi Ambode tó wá sí Russia fún àṣekágbà ìdíje ifé ẹ̀yẹ àgbáyé ti 2018 ló síjú àànú wo àwọn ènìyàn lórúkọ ara rẹ̀.