Ekiti Election: Awọn oludibo ko mọ idi ti wọn fi n yin tajutaju ni Okesha

Ekiti Election: Awọn oludibo ko mọ idi ti wọn fi n yin tajutaju ni Okesha

Awọn ọlọpa yin tajutaju ni ipinlẹ Ekiti leyin ti ọpọlọpọ eniyan bẹrẹ si ni se ayẹwo orukọ lati bẹrẹ si ni di ibo wọn ni ipinlẹ Ekiti agbeegbe Okesha.

Lara awọn oludibo to ba BBC News Yoruba sọrọ fi ẹsun kan awọn ọlọpaa pẹ wọ̀n fi tajutaju lẹ̀ awọn oludibo. Sugbon lara wọn sọ̀ wi pe ẹru o ba awọn.

Awọn eniyan naa fikun wi pe awọn yoo dibo ti asiko ba to.