Ekiti Election: Niyi Adebayọ ní ohun gbogbo ń lọ létò-létò

Ekiti Election: Niyi Adebayọ ní ohun gbogbo ń lọ létò-létò

Gomina tẹ́lẹ̀ ní ìpinlẹ Ekiti, Adeniyi Adebayọ ti sọ ni wọọdu idibo rẹ pe eto idibo naa n lọ ni pẹlẹ-putu, ti ko si si wahala kankan.

Bakan naa lo ni awọn ọlọpaa n sisẹ wọn bo ti yẹ, ti iduro wọn lawọn agọ idibop si n se iwuri fun awọn oludibo lati jade wa dibo.