Ekiti Election: Kọmísánà fétò ìdìbò ní jàǹdùkú já àpótí gbà ní wọ́ọ́dù mẹ́fà

Ekiti Election: Kọmísánà fétò ìdìbò ní jàǹdùkú já àpótí gbà ní wọ́ọ́dù mẹ́fà

Kọmísánà fétò ìdìbò nípìnlẹ̀ Èkìtì, Ọ̀jọgbọ́n Abdulganiyu Raji, lásìkò tó ń bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀, ti se káre sétò ìdìbò tó wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ní ọjọ́ àbámẹ́ta.

Raji ní òun leè fọwọ́ gbáyà pé ètò ìdìbò náà bẹ̀rẹ̀ lásìkò láwọn àgọ́ ìdìbò, àmọ́ omi gínńgín tó ba ojú epo jk nínú ìdìbò náà ni tàwọn jàǹdùkú tó já àpótí ìbò gbà ní àgọ̀ ìdìbò márùn-ún sí mẹ́fà, àmọ́ ó ní èyí kò dá àseyọrí ìdìbò náà dúró.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: