Ekiti Election: Àwòrán bí ètò ìdìbò gómìnà ṣe lọ ní Ekiti

Ẹ wo akojọpọ aworan bi eto idibo gomina ṣe lọ ni ipinlẹ Ekiti.

Awọn ọdọ ní ní Ado Ekiti Okeyinmi
Àkọlé àwòrán Ní kété tí àjọ elétò ìdìbò Nàìjíríà kédé ọ̀jsgban Kayode Fayemi gẹ́gẹ́ bí eni tó jáwé olú borí ni àwọn ará ìlú ti bó sí ìgborláti dáwọ̀ọ́ ìdùnú.
Awọn ara Ekiti
Àkọlé àwòrán Aago mẹjọ̀ owurọ ni awọn oludibo ti jade lati yẹ orukọ wo ati iforukọsilẹ.
Awọn ara Ekiti
Àkọlé àwòrán Awọn arugbo to lọwọọwọ lati yan eni ti wọn fẹ ko jẹ gomina wọn ni Ekiti.
Ekiti
Àkọlé àwòrán Ẹgbẹ oselu marundinlogoji lo dije du ipo fun gomina ipinlẹ Ekiti ni ọdun 2018.
Ekiti
Àkọlé àwòrán Ajo INEC leyin idibo naa sọ wi pe idibo naa lọ ni irọwọrọsẹ laisi si ifarapa.
Ekiti
Àkọlé àwòrán PDP sọ wi pẹ idibo naa ko lọ ni irọwọrọsẹ atiwipe wọn ji ibo gbe ni awọn agbeegbe kan.
Ekiti
Àkọlé àwòrán Witi witi ni awọn eniyan pe jọ lati gbọ esi idibo ni wọọdu ati ekun idibo wọn.
Ekiti
Àkọlé àwòrán John ọmọ Fayẹmi sin ilẹ Naijiria ilẹ baba rẹ̀ gẹgẹ bii olukọni ni Police College to wa ni Ṣokoto lapa ariwa Naijiria.
Ekiti
Àkọlé àwòrán Ile ti mọ, ta lo jawe olubori ni ibeere awọn eniyan ni owurọ kuto ọjọ keji idibo.
Awọn ọdọ yayọ ni òkè ìyìnmi
Àkọlé àwòrán Ilú àdó Ekìtì ní àwọn ará ìlú ti gbòdé láti fi ìdúnú wọn han lóri èsì ìbò.
Ekiti
Àkọlé àwòrán Kayode Fayemi ti ṣe gomina ipinlẹ Ekiti ri laarin Ọjọ kẹrindinlogun, osu kẹwaa, ọdun 2010 si ọjọ kẹẹdogun, osu kẹwaa, ọdun 2014.
Awọn ọdọ ní ní Ado Ekiti Okeyinmi
Àkọlé àwòrán Ní kété tí àjọ elétò ìdìbò Nàìjíríà kédé ọ̀jsgban Kayode Fayemi gẹ́gẹ́ bí eni tó jáwé olú borí ni àwọn ará ìlú ti bó sí ìgborláti dáwọ̀ọ́ ìdùnú.
Ekiti
Àkọlé àwòrán Awọn eekan ninu ẹgbẹ oselu APC ni wọn ki Fayemi ku orire.

Awọn aworan naa wa lati ileesẹ BBC.