‘Awọn Ekiti dibo fun nitori wọn ko fẹ iwa aibọwọ̀ fagba mọ’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

'Òpín yóò débá ìwà jàgídíjàgan ní Ekiti'

Gomina ti wọn sẹsẹ dibo yan ni ipinlẹ Ekiti, Kayode Fayemi, ti so pe awọn eniyan dibo yan oun nitori ìyà àti ìṣẹ́.

Ariwo ati ayọ ni awọn ara Ekiti fi pade Gomina ti wọn sẹsẹ dibo yan naa ni ipinlẹ Ekiti nigba ti o jade si gbangba lẹyin ti Ajọ INEC kede ẹgbẹ oselu APC gẹgẹ bi ẹyi to jawe olubori ninu idibo naa.

Ojogbon Oluṣola Eleka (PDP) ni wọn jọ dije pẹlu awọn miran ni Ekiti.

Amọ, ẹgbẹ oselu PDP ti tako esi ibo naa, ti wọn si sọ pe awọn yoo sa ipa wọn lati fihan wi pe magomago waye ninu eto idibo naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: