'Ìyá Tíṣà lòdì sí kí n mutí, fagbó tàbí sìgá'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Small Doctor: Mi ò fi igbò tàbí sìgá kọrin rí

Ní ìgbà tí ó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ, Small Doctor jk kó di mímọ̀ pé kò dẹrùn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí:

Kíni ẹ mọ̀ nípa àwọn gbajúgbaja Yollywood?

#ShoMoAgeMiNi# Àṣà tó ń dá ìgboro rú

'Obinrin lo mu mi fẹran orin kikọ'