Fídíò akọni obìnrin tó tako híhá ẹ̀há
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Huda Shaarawi: Kò dára kí obìnrin ṣè’yàwó lọ́mọ ọdún mẹ́tàlá

Huda Shaarawi ni obìnrin tó ní ipa rere ní ilẹ̀ Afrika.

Ẹlẹ́hàá ni, tó sì tako bí wọn kò se fún àwọn obìnrin ní àǹfààní láti lọ ilé-ìwé pẹ̀lú àwọn ọkùnrin.

Bákan náà ló tún kẹ̀yìn sí àsà kí ọmọdé-bìnrin máa lọ sílé ọkọ lọ́mọ ọdún mẹ́tàlá, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti se fún-un.

Ó sì dábàá pé ọdún mẹ́rìndínlógún ló yẹ kí wọn máa se ìgbeyàwó fún àwọn obìnrin.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: