Asofin Ekiti: Ọ̀pọ̀ ìdúnkokò-mọ́ni tó ń wá, ló fẹ́ gbẹ̀mí wa

Asofin Ekiti: Ọ̀pọ̀ ìdúnkokò-mọ́ni tó ń wá, ló fẹ́ gbẹ̀mí wa

Olórí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ipinlẹ̀ Ekiti, Kọla Oluwawọle, ṣalaye pé ẹ̀mí àwọn wà nínú ewu ni àwọn kò se ní jókòó títí di Oṣù Kẹ́wàá nígba tí Gomina Ayo Fayose yoo fipò sílẹ̀.

Oluwawọle ni ọ̀pọ̀ ìdúnkokò-mọ́ni tó ń wá láti ọ̀pọ̀ oníruuru ẹ̀dá, ló fẹ́ gbẹ̀mí àwọn, èyí tó mú káwọn fi jókòó sílé.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: