Ekiti Election: Àwọn aráàlú ń tahùn síra wọn lórí ìbò rírà

Ekiti Election: Àwọn aráàlú ń tahùn síra wọn lórí ìbò rírà

Awọn eeyan kan, lasiko idibo gomina ipinlẹ Ekiti ni asa ibo rira, ti wọ́n pe ni ‘See and Buy’, lo gbode kan lasiko ibo naa.