'Àwọn t'ọ́lọ́pàá mú kọ́ ló pa Aborishade'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ikú alága PDP: Ọtọ láwọn tọlọ́pàá gbé ti mọ́'lé

Aṣojú igbimọ majẹkobajẹ ẹgbẹ ọṣelu PDP, Dokita Remi Akitoye, sọ fun ikọ BBC pe, iwadi ti awọn ọlọpàá ṣe lori iku Niyi Aborishade to jẹ́ alaga PDP ní ìjóba ìbílẹ̀ Apapa ko tẹ awọn lọrun.

Awọn agbebọn kan ni Eko yinbọn pa Aborishade lẹyin ipade awọn alaga ẹgbẹ naa to waye ni ọjọ Abaméta ni Eti Ọsa.