Wùmí Toríọlá: Èpè ní Toyin gbémi ṣẹ́ lóri igbéyàwó rẹ̀ tó dàrú

Wumi Toriọla, tíí se òsèré tíátà lóbìnrin, sọ fún BBC Yorùbá lori ìpa tó kó nínú ìgbeyàwó Toyin Abraham pẹ̀lú Adeniyi Johnson, lati ri pe o tọjọ, amọ tó papa forí sánpọ́n.

Wumi ni òun rí bí àwọn akẹẹgbẹ́ òun kan, se ń bu ẹnu àtẹ́ lu àseyọrí tí ọ̀pọ̀ òsèré tíátá ń gbé sórí ìtàkùn àgbáyé bíi ìwà ìlara.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: