Ǹ jẹ́ o leè fi àmì sórí ‘Àgbàlagbà-akàn’ ?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Báwo lo se gbọ́ èdè Yorùbá sí ?

Àmì jẹ́ ara èdè Yorùbá, tó fi ń jẹ́ kí èdè náà rẹwà púpọ̀.

Sùgbọ̀n ó dàbí ẹni pé àmì ọ̀rọ̀ yìí, nínú èdè Yorùbá, ti ń lọ sí òkun ìgbàgbé.

Ara ọ̀nà láti máa rán àwọn ọmọ Yorùbá léti pàtàkì àmì ọ̀rọ̀ ló mú kí BBC Yorùbá bọ́ síta láti máa bèèrè pé káwọn èèyàn kan fi àmì sí orí ‘Àgbàlagbà-akàn’ .

Àwàdà kẹrí-kẹrì gbá à ni fídíò yìí.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: