Akeeb Kareem: Iléesẹ́ tó gbé àwo orin Ámẹ̀bọ jáde yàn mi jẹ

Akeeb Kareem: Iléesẹ́ tó gbé àwo orin Ámẹ̀bọ jáde yàn mi jẹ

Láàrin àkókò ọ̀dún 60s sí 80s ni àwọn àwo orin Akeeb Kareem, tí ó tún ńjẹ́ Blackman gbilẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Akeeb Kareem ti gbé iṣẹ́ orin kíkọ tayọ agbègbè orílẹ̀èdè Nàìjíríà nìkan.

Lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ, Akeeb ni ibasepọ oun ati awọn ileesẹ ilẹ okeere to n gbe awo orin jade ko lọwọ magomago ninu rara.

Amọ o ni, igba ti oun gbiyanju lati se awo orin ni Naijiria, ni wọn ko fun oun ni ẹtọ toun lori awo orin ti oun gbe jade, tii se Amẹbọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: