'Ó ju wákàtí kan lọ kí àwọn Nọ́ọ̀sì tó dá sí wá'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìjàmbá iná afárá Ọtẹdọla: Wọ́n ń parọ́ wí pé ọ̀fẹ́ lògùn

Níbi tí ìjọba tí ṣèpàdé pẹ̀lú àwọn ẹbí àwọn tó fara gbá níbi iṣẹ̀lẹ̀ afárá Ọ̀tẹ́dọlá nílùú Eko, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn ní àwọn oṣìṣẹ́ ilé ìwòsan ń ṣe lòdì sí àṣẹ́ tí ìjọba pa.

Àwọn òṣìṣẹ́ NAN ya bo Abuja fún ẹ̀tọ́ wọn

Fatai Akinbade kúrò lẹ́gbẹ́ òṣèlú PDP l'Ọ́ṣun

Ṣé ẹ rántí orin - 'Má ṣe jẹ́jẹ́ ma wà mi lọ'?