Wo adájọ́fẹ̀yìntì tó ń léwájú àwọn olùwọ́de l'Ọ́ṣun
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Onídájọ́ Fọlahanmi Oloyede léwájú ìwọ́de òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì fún ọjọ́ mẹ́ta l'Ọ́ṣun

Adajọ fẹyinti Fọlahanmi Oloyede kii ṣe ajeji lawujọ ajafẹtọ araalu, paapaa awọn oṣiṣẹ ni ipinlẹ Ọṣun.

Laipẹ yii lo tun ṣiwaju awọn oṣiṣẹfẹyinti nipinlẹ Ọṣun lasiko iwọde ọlọjọ mẹta ti wọn ṣe lati fi beere fun sisan ẹtọ ifẹyinti pẹlu ajẹẹlẹ owo ifẹyinti oloṣooṣu wọn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: