Lion Chaser: Richard, ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún se iná tó ń lé kìnìún

Lion Chaser: Richard, ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀dógún se iná tó ń lé kìnìún

Ní orílẹ̀-èdè Kenya, Richard jẹ́ ọ̀dọ́mọdé kan tí ìjọba fún ní ẹkọ́-ọ̀fẹ́ ní iléèkọ́ kan tó gbajú-gbajà lágbàáyé, nítorí pé ó se àwárí ìmọ̀ ẹ̀rọ iná kan tó ń lo òòrùn láti fi lé kìnìún ní ìlú rẹ̀.

Àwọn kìnùún yìí ló máa ń pa àwọn èèyàn àti àwọn àgùtàn rẹ̀, àmọ́ tó se àwárí rẹ̀, nígbà tó wà lọ́mọ ọdún mọ́kànlá pé àwọn kìnìún yìí máa ń bẹ̀rù iná alágbèéká.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

BBCINNOVATORS