Ìyá ìbarùn-ún: Mo rò pé ‘scan’ ń pa irọ́ niní oyún pé márùn-ún ni màá bí

Iyalẹnu lo maa n jẹ fun ọpọ eniyan lati bi ọmọ meji abi mẹta ni ẹẹkan soso, ka ma sẹsẹ sọ ti ọmọ marun-un.

Bẹẹ ni ọrọ ri pẹlu idile Imudia ati Oluwakẹmi Uduehi, nigba ti wọn bi ọmọ marun-un ni ẹẹkan soso.

Iya ibarun-un naa sọ fun BBC Yoruba pe, oun ko lee jade bi o se wu oun nitori awọn ibarun-un naa.

Amọ o wa n dupẹ lọwọ Ọlọrun pe ẹẹkan pere ni oun yoo jẹ irora ọmọ bibi pẹlu ibarun-un ti oun bi naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: