Àwọn obìnrin Dahomey: Àwọn obìnrin ilẹ Áfríkà ti wọn yii itan pada re e

Àwọn obìnrin Dahomey: Àwọn obìnrin ilẹ Áfríkà ti wọn yii itan pada re e

Ipa ribiribi ni awọn obinrin ilẹ Afirika ti wọn yii itan pada wọn yii ko ni ijọba ilẹ Dahomey, ti a mọ si orilẹede Benin lode oni.

Wọn jagun nigba ti imunisin awọn ara ilẹ Yuroopu peleke.

Awọn obinrin wọn yii lo n sọ ọba wọn amọ wọn di akikanju ologun ti ko foya lati koju ẹnikẹni.