Babatunde Fashola: Iná mọ̀nàmọ́ná ní Nàìjíríà ti wọ 7000 Megawaati

Babatunde Fashola Image copyright @FMPWH
Àkọlé àwòrán Babatunde Fashola
Òpó iná Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ọ̀kan lára ìpènijà tó ń kójú orílẹ̀èdè Naijiria ní ìpèsè iná mọ̀nàmọ́ná tó gbòrò fún àwọ̀n ọmọ Naijiria.

Minisita fun ọrọ ipese ina, isẹ ode ati ile gbigbe, Babatunde Fashola ni ipese ina mọnamọna ti wọ ẹgbẹrun meje mẹgawaati lorilẹede Naijiria.

Fashola sọ eyi nigba to n se ipade pẹlu awọn adari ẹka to wa ni abẹ ile isẹ to n risi ipese ina, isẹ ati ile gbigbe ni ilu Calabar.

Ninu ọrọ rẹ, O ni ipese ina mọnamọna ni Naijiria ti gboro si bayii, amọ ise pupọ si wa lati se.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionỌ̀ṣọ́ Aṣọ Òkè ti kọjá lílo ìlẹ̀kẹ̀ níkan

Ọkan lara ipenija to n koju orilẹede Naijiria ni ipese ina mọnamọna to gboro fun awọn ọmọ Naijiria.