Ọ̀pọ̀ èrò gbàgbọ́ pé òrìṣà ni àfín jẹ́ láwùjọ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

'Ìbí kò ju ìbí, Èèyàn bíi tiyín ni àfín, ẹ dẹ́kun dídẹ́yẹsí àfín'

Bí Ọlọrun ṣe dá ààwọ̀ ara wa nìyí, àfín kò yàtọ̀!

Adeọṣun Fọlaṣade ba BBC Yorùbá sọrọ lórí ìhùwàsí awọn eniyan ti wọn ba ti ri afin ati bi eyi ṣe le ṣakoba fun iru afin bẹẹ ni awujọ.

O gba awọn eniyan nimọran pe 'E ma fi ọ̀bọ lọ àfín mọ́ nitori pe ìbí kò ju ìbí'.