Ayefẹlẹ: Orí ìkúnlẹ̀ ni ìyàwó mi wà, tó ń bẹ gómìnà, láti 11pm si 4am

Ayefẹlẹ: Orí ìkúnlẹ̀ ni ìyàwó mi wà, tó ń bẹ gómìnà, láti 11pm si 4am

Alaye ijọba ipinlẹ Ọyọ ati ti Yinka Ayefẹlẹ lo n tako ara wọn lori ọrọ ileesẹ redio Ayefẹlẹ ti ijọba ipinlẹ Ọyọ wo.

Ninu ipade akọroyin ọtọọtọ ti wọn se, Ayefẹlẹ ni oun n san gbogbo owo to yẹ fun ijọba lori ile ati ilẹ naa, amọ ijọba ipinlẹ Ọyọ ni ohun ti Ayefẹlẹ ni oun fẹ fi ilẹ naa se, lasiko to n gba iwe ilẹ lọdọ ijọba, kọ lo fi se.

Awọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: