Ìgbeyàwó Fayose: Ìjó Shaku-shaku ni gómìnà fi dárayá

Igbeyawo alarinrin naa waye laarin Tomilọla Fayose ati Arẹwa Ọdunlade lọjọ Satide, ọjọ kejidinlogun, osu kẹjọ ọdun 2018.

Àkọlé àwòrán,

Asọ oyinbo ni gomina wọ lati fa ọmọ rẹ fun ọkọ ni kootu

Àkọlé àwòrán,

Baba ati iya iyawo ni wọn se bii oloyinbo nibi igbeyawo oloruka ti Tomi Fayose ati Arẹwa Ọdunlade se

Àkọlé àwòrán,

Awọn ẹbi tọkọ-taya tuntun ti parada si asọ ibilẹ wa

Àkọlé àwòrán,

So bẹbẹ fẹ, abi o ko bẹbẹ fẹẹ ? Mo bẹbẹ fẹ ni ọkọ iyawo atawọn ọrẹ rẹ n sọ.

Àkọlé àwòrán,

Ọmọ to jọ ‘Daddy’ gan ree., oju to n sọrọ

Àkọlé àwòrán,

Ololufẹ, maa fẹ ọ titi aye ni tọkọ-taya tuntun n sọ fun ara wọn

Àkọlé àwòrán,

Ijo shaku-shaku baba iyawo yii, ara ọtọ ni

Àkọlé àwòrán,

Haa, o ga ju. Fayose ko kẹrẹ ninu ijo Shaku-shaku

Àkọlé àwòrán,

Iyawo yoo bi isun, yoo bi iwalẹ

Àkọlé àwòrán,

Iya ati baba mo mi lọ, ẹfi adura sin mi o

Àkọlé àwòrán,

Tomilọla, ile ọkọ ya, ki ẹlẹda awọ̀n obi rẹ sin ọ lọ

Àkọlé àwòrán,

Iyawo dun lọsingin, ọkọ tun mi gbe