Bọlanle Ninalowo: Ọ̀rẹ́ lásán àti olóore mi ni Mercy Aigbe

Bọlanle Ninalowo: Ọ̀rẹ́ lásán àti olóore mi ni Mercy Aigbe

Bọlanle Nínálowó, ti i se Ìlúmọ̀ọ́ká òsèré tíátà lédè Yorùbá sọ̀ pé, ọ̀nà láti gbé nǹkan re se sílẹ̀ fún àwọn ọmọ òun ló jẹ òun lógún báyìí.

Nínálowó, lásìkò tó ń bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ ní, kò sí ìfẹ́ ìkọ̀kọ̀ kan-kan láàrin òun àti Mercy Aigbe, sùgbọ́n olóore òun ni.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: