Ọ̀ọ̀ni bá Buhari sọ̀rọ̀ lórí dídá iṣẹ́ sílẹ̀ fáwọn ọ̀dọ́

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Ọ̀ọ̀ni bá Buhari sọ̀rọ̀ lórí dídá iṣẹ́ sílẹ̀ fáwọn ọ̀dọ́
Ọọni ti ilẹ ifẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusi Ọjaja II ṣepade pẹlu Aarẹ Muhammadu Buhari ni ọjọ Iṣẹgun.
Nipade ọhun to waye nile aarẹ, Aso rock nilu Abuja ni Ọọni ti mu agba oludokoowo kan, Sharif Ahmad Bin Zuhir Bin Mohammad Bin Jaber Al Natour sodi lati jiroro lori idokoowo.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Ni ọjọ Aje ni Ọọni Adeyẹye Ogunwusi tọwọ bọ iwe adehun pẹ̀lú àjọ kan láti ilẹ̀ Arab ti Sharif Ahmad Bin Zuhir Bin Mohammad Bin Jaber Al Natour n dari láti dá Iléesẹ́ ohun ọ̀gbín àti ọ̀sìn nílẹ̀ Ìfẹ́.
Gẹgẹ bii atẹjade kan lati aafin Oodua ṣe sọ, ipade naa yoo da lori ajọṣepọ to lee waye laarin ileeṣẹ naa ati ijọba apapọ fun idaṣẹsilẹ fun awọn ọdọ, idagbasoke ati ironilagbara.
Bọde George: Àwọn èèyàn mọ ẹni to yìnbọn pa Adeniyi Aboriṣade
Wọ́n rò pé mo ya wèrè ni Saudi lẹ́yìn ikú ọkọ mi
'Mi o fẹẹkan ni mo fẹ dupo aarẹ'