Omisore, Akinbade ní jìbìtì ni N10,000 ìjọba àpapọ̀
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìdìbò Ọṣun: Omisore, Akinbade ní jìbìtì ni N10,000 ìjọba àpapọ̀

Oludije fun ipo gomina ni labẹ aṣia ẹgbẹ oṣelu SDP, Iyiola Omíṣore ni ẹgbẹrun mẹwa naira ti ijọba apapọ ya awọn ọlọja ni Ipinlẹ Ọṣun kii ṣe oriire. Bẹẹ naa ni, Fatai Akinbade, to jẹ oludije labẹ aṣia ADC ni, ọgbọn ati ra ibo ni.

Agbẹnusọ Akinbade, Kayode Oladeji, lo ba ikọ BBC sọrọ lorukọ oludije naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: