'Àwa oní Tíátà kìí gbélé, àwọn ọmọ wa sì nílò wa'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Lanko Adeọla Ṣorẹmi: Ọlọrun nìkan ló ń bá wa to ilé wa

Adeọla Ṣorẹmi ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Princess Lanko ti bu ẹnu àtẹ́ lu kí àwọn òṣèré má máa ráyé fún ẹbí wọn léyìí tó ni òun náà jẹ́ ọ̀kan.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí:

Ẹgbẹ́ ọmọ Nàìjíríà ra fọ́ọ̀mù fún Buhari

'ìjọba àpapọ̀ fẹ fi N10,000 rà ìbò ni'

Ààwẹ̀ gbẹ̀mí ọmọ Naijiria ní orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà

Kí lẹ ò mọ̀ nípa àwọn obinrin Yollywood yìí?