Josh Posh: Irun mií tó ‘Posh’, làwọn èèyàn se ń pè mí ní Josh Posh

Josh Posh: Irun mií tó ‘Posh’, làwọn èèyàn se ń pè mí ní Josh Posh

Joshua Roberts, tawọn eeyan n pe ni Josh Posh jẹ ọdọmọde olorin to gba iwuri orin kikọ lede Yoruba lati ọdọ iya rẹ.

Josh Posh sàlàyé pé kékeré ni òun ti máa ń gbé àbúrò òun sí ẹsẹ̀ láti kọrin fún-un.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: