Bi iṣẹ perfume tita ti ṣe yí ìgbésí ayé Adéwálé Aladejana padà
Bi iṣẹ perfume tita ti ṣe yí ìgbésí ayé Adéwálé Aladejana padà
Gbogbo igba ti Adéwálé Aladejana ba n rántí bí o tí ṣé bẹrẹ iṣẹ perfume tita,n'isẹ ní inú rẹ má n dùn.
Iṣé perfume tita kí ṣé nkán tí Adéwálé Aladejana yan láàyò ṣùgbọ́n nígbàtí anfààní rẹ sì sílẹ lati bere owo naa,n'isẹ ní o sọ di ilumọka.
''₦30000 ní mo fí bẹrẹ iṣẹ yí. Lẹyin oṣù mẹta,owó náà di irú o digba mọ mi lọwọ.''