Bọla Tinubu: Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun kò ní owó mi lọ́wọ́

Bọla Tinubu: Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun kò ní owó mi lọ́wọ́

Asiwaju fẹgbẹ oselu APC nilẹ yii, Oloye Asiwaju Bọla Ahmed Tinubu, ti sọ ni ilu Oṣogbo, lasiko to lewaju ikọ ipolongo ẹgbẹ oṣelu APC lọ si aafin Ataọja ti ilu Oṣogbo pe ki wọn tẹ́wọ́gba oludije fun ipo gomina fẹ́gbẹ́ oselu APC nipinlẹ́ Ọsun, Gboyega Oyetọ̀la, nitori ko ni ji wọ̀n wọ̀n lowo.

Tinubu wa n beere pe, "Ti wọ̀n ba n sọ̀ pe Jagaban, Asiwaju wa fi eeyan kan jẹ́ gaba l‘Ọsun lati maa ko owo yin, mo wa n beere pe eelo gan lk ni lọwọ ?"

Tinubu ni ilakaka oun lo wa lati ran awọ̀n eeyan ipinlẹ́ Ọsun lọwọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: