Ayo Ajewole: Kí ló fàá tí Dele máa ń ṣe àìgbọ́ràn sí Wòlíì?

Ayo Ajewole: Kí ló fàá tí Dele máa ń ṣe àìgbọ́ràn sí Wòlíì?

Òṣèré onísẹ́ ìhìnrere Krìstẹ́nì ni ọpọ̀lọpọ̀ mọ Ayo Ajewole, Wòlíì àgbà sí tẹ́lẹ̀ kò tó wá yà sí ṣíse àwàdà pọ́nbélé nínú gbogbo eré ìtàgé rẹ̀.

Ẹ̀wẹ̀, ó sọ ìdí tí pípànìyàn lẹ́rìín fi ṣe pàtàkì nínú eré rẹ̀.