‘Ọ̀rẹ́ mi ní kí n fi ‘acid’ sí oúnjẹ ọmọ mi’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìyá àkàndá ẹ̀dá: Àwọn ẹbí mi fẹ́ kí n pa ọmọ mi torí ó jẹ́ àkàndá ẹ̀dá

Ajọ to n ja fun ẹtọ awọn akanda ẹda lagbaye (Disability Rights International) sọ wi pe, ni orilẹede Kenya, Ida mẹrindinlaadọrin iya akanda ẹda lo ni, awọn mọlẹbi ati ara ma n gbe ẹmi awọn gbọna lati pa awọn ọmọ wọn to jẹ akanda.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: