Sola Sobowale: Iṣẹ́ tí Ọlọ́run kọ mọ́ mi ni mò ń ṣe

Sola Sobowale: Iṣẹ́ tí Ọlọ́run kọ mọ́ mi ni mò ń ṣe

Gbajúgbajà tó tún jẹ́ àgbà ọ̀jẹ̀ òṣèré Yollywood, Sola Sobowale sọ nípa ìrìn àjò rẹ̀ dé inú iṣẹ́ Tíátà, àwọn ìpèníjà, àṣeyọrí tó fi mọ́ kùdìẹ kudiẹ tó ṣeéṣe kí òṣèrè bá pàdé nínú iṣẹ́ tí wọ́n yàn láàyò.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Kini Sola Sobowale tun so?

Ogbontarigi osere yii rọ awon osere ni imọran.

O soro nipa irinajo aye rẹ̀ ati awon ohun to ti la koja ri ko to di eni ajitan ina wo bayii.

O tun menuba ohun to wu u lati se fun awujọ lọ́ja iwaju.