'Ọọ̀nì ńlá méjì ní wọ́n jọ ń gbé nínú iyàrá'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ejò Sebe, Ọká, òjòlá àti àkeèké jẹ́ alábagbé Phillipe

Ali àti Gator jẹ́ ìbejì ọọ̀nì ti Phillipe jọ wà ninu iyàrá.

Àwọn alantakun to tobi pupọ jẹ ohun iṣere fun Phillipe Gillet to jẹ ọmọ ilẹ̀ Faranse.

Awọn eniyan Yoruba gbà pe inu igbo ni èranko afayafa n gbé ati pe wọn lewu pupọ.

Awọn ogboju ọdẹ nikan lo le mu wọn looyẹ afi ti àwọn omode ba tun ni oore ọfẹ lati lọ wo wọn ni ọgba ẹranko.

Ọmọlóòkú d'èrò ọ̀run níbi ìsìnkú ìyá rẹ̀

A ju ara wa lọ, ìjàkadì kọ́; àṣà Yorùbá yàtọ̀!

'Oògùn olóró máa ń jẹ́ ki n bá ara mi jà, ti màá ṣerami léṣe'

Gèlè ìyàwó láàrín ìṣẹ́jú mẹ́ta kẹ̀?