‘Sọ fún ara rẹ pé o lè se ohun to ní lọ́kàn láti se láì sí ìbẹ̀rù’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kanya Sesser: láti kekere ni ìyá mí ti kọ̀mí sílẹ̀ ṣùgbọ́n n kò ṣagbe

'Sọ fún ara rẹ pé o lè se ohun too ní lọ́kàn láti se láì sí ìbẹ̀rù'

Omobinrin arewa Kanya sesser ti wọn bi lai ni ẹsẹ, ti ni oun se tan lati yi oju ti awọn eniyan fi n wo ẹwa ati arẹwa pada.

Kanya ti iya rẹ kọ silẹ lati kekere jẹ akinkanju obinrin to n sọrọ iwuri fun awọn eniyan kaakiri.

O n kopa ninu ọpọlọpọ ere idaraya pẹlu ere sisa lori yinyin.

Akanda ọmọbinrin naa wa parọwa si awọn ọdọ lati ni igbagbọ ninu ara wọn pe ko si ohun kankan to soro lati se fẹni to ba ni afojusun.

Kanya gbà pé àìlera kò yẹ́ kó sọ eeyan di alagbe rárá ati pé iyẹn kò ni ki eeyan má gbe igbe aye alaafia.

Related Topics