Ademọla Adebayọ: Àwọn Bàbá ìsàlẹ̀ olóṣèlú kan wà...

Ademọla Adebayọ: Àwọn Bàbá ìsàlẹ̀ olóṣèlú kan wà...

Olùdíje kan fún ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Ogun lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú Alliance for New Nigeria, Ademọla Adebayọ ní àwọn bàbá ìsàlẹ̀ kan dára, nígbàtí àwọn míràn máa ń du àpò ara wọn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: